Asaba Anthem | Orinakanṣe Ilú Asába
ASABA ILU TA BI MI
ASABA ILU MI OWON
ILU TO N TU NI LARA
TON FANI M’ORA
ILU TON
GBE NI NIJA
ILU MI OWON
OMO OLUFALOYE NILE LOKO
EMI KOLE GBAGBE ASABA
ILU TA BI MI
GBE MIO, ASABA GBE MIO MO TI KOREDE
GBE MI O, ASABA GBE MIO JEN KOREWOLE