I want first to thank God for the opportunity to live to see the History of ASABA in published form. For so long, we have relied on oral history recited from generation to generation. The sustained effort of the Committee that compiled our history from various records is indeed very commendable. This is indeed a very noble beginning. This history will continually be updated as time goes by and new events unfold.
All sons and daughters of Asaba at home and abroad, including those dispersed to various localities far and near as a result of the internecine wars, can now proudly refer to this authentic history, now published in English and Yoruba languages.
I implore you all to identify more closely with your proud origin by always chanting our famous Anthem.
Long live Asaba. Olufaloye a gbe wa o.

Siwaju, mo dupe ni ọwọ Ọlọrun ti O fun mi ni anfaani ni ọjọ oni lati ri akọsilẹ itan ilu Asaba. Fun igba pipẹ ni oti je wipe itan ati ẹnu de ẹnu ni ati ngbọ ti a si n muu lo lati sọ nipa bi ilu Asaba ti ṣẹ tabi waye. A dupe pupo lọwọ awọn igbimọ ti wọn tiraka lati se iwadi ti o muna doko ni orisirisi ọna nipa itan ilu Asaba ti wọn si gbiyanju la ti kọ ọ silẹ ati lati tẹ ẹ jade.
Iṣẹ yi dun mọ wa ninu pupọ a si ni igbagbọ wipe ko ni mọ bayi nitoripe bi ọjọ ba ẹe n gori ọjọ ti igba naa si nyi ni a o maa ṣe atunṣe iwe itan yi lati ri pe owa ni ẹkun rẹrẹ pẹlu awọn nnkan ọtun ti o ba n ṣẹlẹ. Bayi, gbogbo ọmọ bibi ilu Asaba lọkunrin, lobinrin nile, loko tabi ti wọn tẹdo lẹhin odi nitori iwajẹ tabi nipasẹ ogun le ri itan yi ka yala ni ede Yoruba tabi Gẹẹsi.
Mo rọ gbogbo wa lati ri wipe a ka itan yi a si mọọ lati le mọọ mulo lati igba de igba ati paapaajulọ orinakanṣe ilu Asaba ti awa ati awọn ọmọ wa le maa kọ lati maa ran wa leti iṣẹda ati orisun wa.Olufaloye aa gbe wa o. Ilu Asaba ko nii parun o.
Oba Ezekiel Oyeniyi Oyewusi Osuntoyinbo II
Alasaba ti Ilu Asaba